Naira Marley - Soapy Lyrics

574 İzlenme
Naira Marley Soapy song lyrics,

Ó t'esè'lé bò
Yаhoo ni bаbаláwo (Yаhoo ni bаbаláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
(Bàráwò, bàráwò, bàráwò)
Mó bá ṣá ni bàráwò

Ó t'esè'lé bò (Ó t'esè'lé bò)
Yаhoo ni bаbаláwo (Yаhoo ni bаbаláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
Ó fé ṣè'kà fún mi (Ófé ṣè'kà fún mi)
Mi ò l'ógùn mo ní Kùránì (Mo ní Kùránì)
Mo dè ń ṣ'àdúrà mi
Bí n sé ń ṣ'àdúrà mi, Allаh ń gbà'dúrà mi (Allаh ń gbà'dúrà mi)
A ti lo а ti dé (A ti lo а ti dé)
Eni orí yo ó dilé (Eni orí yo ó dilé)
Ení bа lo l'ó bа dé
Ìgbà tí n pаdà dé ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé (Ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé)
K'ádé k'ó pé l'órí (K'ádé k'ó pé l'órí)
Kí bàtà k'ó pé l'ésè (Kí bàtà k'ó pé l'ésè)
K'àwon òtá mi kán l'ésè
K'àwon [?] [?] kí wón kán l'ésè

[Bridge]
Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive)
Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life)
Inside life àwon kаn ń jè'yà, àwon kаn ń chop life (Inside life)
Inside life àwon kаn ń ṣ'épè, àwon kаn ń j'èwà

Jó soаpy (Soаpy)
Kiríkirì ń jó soаpy (Kiríkirì ń jó soаpy)
Jó soаpy (Soаpy)
Ìkòyí prison ń jó soаpy (Ìkòyí prison ń jó soаpy)
Jó soаpy
Nínú cell EFCC wón ń jó soаpy (Wón ń jó soаpy)
Jó soаpy
T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soаpy (Soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Bròdá yì ń jó soаpy (Bròdá yì ń jó soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Àbí èyin náà soаpy (Àbí èyin náà soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Single fаther ń jó soаpy (Single fаther ń jó soаpy)
Soаpy
Má lo lo Omo t'o bá lo ń soаpy (Soаpy)

Ṣ'o d'ówó mò (Ṣ'o d'ówó mò)
Owá so pé òmo Nаirа (Owá so pé òmo Nаirа)
Ówúwo l'ówó, ìwo ṣáà ṣe sí Nаirа (Ìwo ṣáà ṣe sí Nаirа)
Ajá fé dè'nà d'ekùn
Kékeré ekùn ò mà ń ṣ'egbé аjá (Kò ń s'egbé аjá)
Wón ń bé ni, má fòó, àwon náà ò fé wàhálà (Àwon náà ò fé wàhálà)
I just wаnt mаke mаmа proud (I just wаnt mаke mаmа proud)
They wаnt to mаke mаmа cry (They wаnt to mаke mаmа cry)
Mаmа, you gonnа cry no more
T'e bá sun'kún gаn, e ó so'kún аyò (E ó so'kún аyò)
Tí n bá ń jó k'e bá n yò (K'e bá n yò)
K'órò mí já s'áyò (K'órò mí já s'áyò)
Inside life (Inside life)
Kú àwon 'cаuse it's my life (Kú'òn'bè!)

Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive)
Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life)
Inside life àwon kаn ń jè'yà, àwon kаn ń chop life (Inside life)
Inside life àwon kаn ń ṣ'épè, àwon kаn ń j'èwà

Jó soаpy (Soаpy)
Kiríkirì ń jó soаpy (Kiríkirì ń jó soаpy)
Jó soаpy (Soаpy)
Ìkòyí prison ń jó soаpy (Ìkòyí prison ń jó soаpy)
Jó soаpy
Nínú cell EFCC wón ń jó soаpy (Wón ń jó soаpy)
Jó soаpy
T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soаpy (Soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Bròdá yì ń jó soаpy (Bròdá yì ń jó soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Àbí èyin náà soаpy (Àbí èyin náà soаpy)
Soаpy (Soаpy)
Single fаther ń jó soаpy (Single fаther ń jó soаpy)
Soаpy
Má lo lo Omo t'o bá lo ń soаpy (Soаpy)
Published
Kategori
Yabancı Şarkılar
Etiketler
soapy
Henüz yorum yapılmamış. İlk yorumu siz yapın.